Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 26:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó tó lọ sí Gerari, Ọlọrun farahàn án, ó sì kìlọ̀ fún un pé kò gbọdọ̀ lọ sí Ijipti, kí ó máa gbé ilẹ̀ tí òun sọ fún un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:2 ni o tọ