Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 25:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ń ti ara wọn síhìn-ín sọ́hùn-ún ninu rẹ̀, ó sì wí pé, “Bí ó bá jẹ́ pé báyìí ni yóo máa rí, kí ni mo kúkú wà láàyè fún?” Ó bá lọ wádìí ọ̀rọ̀ náà wò lọ́dọ̀ OLUWA.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:22 ni o tọ