Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 25:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Isaaki di ẹni ogoji ọdún, ó fẹ́ Rebeka. Rebeka jẹ́ ọmọ Betueli, ará Aramea, tí ń gbé Padani-aramu, ó sì tún jẹ́ arabinrin Labani, ara Aramea.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:20 ni o tọ