Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 25:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni ọmọkunrin Iṣimaeli. Wọ́n jẹ́ ọba ẹ̀yà mejila, orúkọ wọn ni wọ́n sì fi ń pe àwọn ìletò ati àgọ́ wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:16 ni o tọ