Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 23:8 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Bí ẹ bá fẹ́ kí n sin òkú aya mi kúrò nílẹ̀ nítòótọ́, ẹ gbọ́ tèmi, kí ẹ sì bá mi sọ fún Efuroni ọmọ Sohari,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23

Wo Jẹnẹsisi 23:8 ni o tọ