Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 23:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sọ fún Efuroni lójú gbogbo wọn, ó ní, “Ṣugbọn, bí ó bá ti ọkàn rẹ wá, fún mi ní ilẹ̀ náà, kí n sì san owó rẹ̀ fún ọ. Gbà á lọ́wọ́ mi, kí n lè lọ sin aya mi sibẹ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23

Wo Jẹnẹsisi 23:13 ni o tọ