Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, Ọlọrun dán Abrahamu wò, ó ní, “Abrahamu!” Abrahamu dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22

Wo Jẹnẹsisi 22:1 ni o tọ