Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 21:33-34 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Abrahamu gbin igi tamarisiki kan sí Beeriṣeba, ó sì ń sin OLUWA Ọlọrun ayérayé níbẹ̀.

34. Abrahamu gbé ilẹ̀ àwọn ará Filistia fún ìgbà pípẹ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21