Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ jókòó ní òkèèrè, ó takété sí i, ó tó ìwọ̀n ibi tí ọfà tí eniyan bá ta lè balẹ̀ sí, nítorí ó wí ninu ara rẹ̀ pé, “Má jẹ́ kí n wo àtikú ọmọ mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21

Wo Jẹnẹsisi 21:16 ni o tọ