Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 21:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bẹ Sara wò gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, ó sì ṣe fún un gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀.

2. Sara lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan fún Abrahamu lẹ́yìn tí ó ti di arúgbó, ní àkókò tí Ọlọrun sọ fún un.

3. Abrahamu sọ ọmọkunrin náà ní Isaaki.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21