Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu sọ fún àwọn ará Gerari pé arabinrin òun ni Sara aya rẹ̀, Abimeleki, ọba Gerari bá ranṣẹ lọ mú Sara.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20

Wo Jẹnẹsisi 20:2 ni o tọ