Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 19:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mú kí baba wọn mu ọtí waini ní alẹ́ ọjọ́ náà pẹlu, èyí àbúrò lọ sùn tì í, baba wọn kò mọ ìgbà tí ó sùn ti òun, bẹ́ẹ̀ ni kò mọ ìgbà tí ó dìde.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19

Wo Jẹnẹsisi 19:35 ni o tọ