Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ̀yin oluwa mi, ẹ jọ̀wọ́ ẹ yà sí ilé èmi iranṣẹ yín, kí ẹ ṣan ẹsẹ̀ yín, kí ẹ sì sùn ní alẹ́ yìí, bí ó bá di ìdájí ọ̀la, kí ẹ máa bá tiyín lọ.” Ṣugbọn wọ́n dáhùn pé, “Ó tì o! ìta gbangba láàrin ìlú ni a fẹ́ sùn.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19

Wo Jẹnẹsisi 19:2 ni o tọ