Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin náà bá kúrò níbẹ̀, wọ́n gba ọ̀nà Sodomu lọ, ṣugbọn Abrahamu tún dúró níwájú OLUWA níbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:22 ni o tọ