Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nígbà tí Sara gbọ́ pé òun óo bímọ, ó rẹ́rìn-ín sinu ara rẹ̀, ó ní, “Lẹ́yìn ìgbà tí mo ti di arúgbó, tí ọkọ mi náà sì ti di arúgbó, ǹjẹ́ mo tilẹ̀ tún lè gbádùn oorun ọmọ bíbí?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:12 ni o tọ