Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 17:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Abrahamu dojúbolẹ̀, ó búsẹ́rìn-ín, ó sì wí ninu ara rẹ̀ pé, “Ọkunrin tí ó ti di ẹni ọgọrun-un (100) ọdún ha tún lè bímọ bí? Sara, tí ó ti di ẹni aadọrun-un ọdún ha tún lè bímọ bí?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17

Wo Jẹnẹsisi 17:17 ni o tọ