Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 16:15-16 BIBELI MIMỌ (BM)

15. Hagari bí ọmọkunrin kan fún Abramu, Abramu sì sọ ọmọ náà ní Iṣimaeli.

16. Abramu jẹ́ ẹni ọdún mẹrindinlaadọrun nígbà tí Hagari bí Iṣimaeli fún un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 16