Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọti tí ó bá Abramu lọ náà ní ọpọlọpọ ẹran ọ̀sìn ati agbo mààlúù ati ọpọlọpọ àgọ́ fún ìdílé rẹ̀ ati àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13

Wo Jẹnẹsisi 13:5 ni o tọ