Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA fara han Abramu, ó wí pé, “Àwọn ọmọ ati ọmọ ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ yìí fún.” Abramu bá tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ fún OLUWA tí ó fara hàn án.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12

Wo Jẹnẹsisi 12:7 ni o tọ