Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo súre fún àwọn tí wọ́n bá súre fún ọ, bí ẹnikẹ́ni bá sì fi ọ́ bú, n óo fi òun náà bú. Nípasẹ̀ rẹ ni n óo bukun gbogbo ìdílé ayé.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12

Wo Jẹnẹsisi 12:3 ni o tọ