Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 12:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA fi àrùn burúkú bá Farao ati gbogbo ìdílé rẹ̀ jà nítorí Sarai, aya Abramu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12

Wo Jẹnẹsisi 12:17 ni o tọ