Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe fọ́n wọn káàkiri sí gbogbo orílẹ̀ ayé, wọ́n pa ìlú náà tí wọn ń tẹ̀dó tì.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11

Wo Jẹnẹsisi 11:8 ni o tọ