Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 11:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu ati Nahori ní iyawo, Sarai ni orúkọ iyawo Abramu, orúkọ iyawo ti Nahori sì ni Milika, ọmọbinrin Harani. Harani ni baba Milika ati Isika.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11

Wo Jẹnẹsisi 11:29 ni o tọ