Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 11:22-24 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Nígbà tí Serugi di ẹni ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori.

23. Ó tún gbé igba (200) ọdún sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Nahori, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

24. Nígbà tí Nahori di ẹni ọdún mọkandinlọgbọn ni ó bí Tẹra.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11