Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Eberi tún gbé ojilenirinwo ó dín mẹ́wàá (430) ọdún sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Pelegi tán, ó tún bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11

Wo Jẹnẹsisi 11:17 ni o tọ