Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Ṣemu bí Apakiṣadi tán, ó tún gbé ẹẹdẹgbẹta (500) ọdún sí i láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11

Wo Jẹnẹsisi 11:11 ni o tọ