Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran Noa nìyí: àwọn ọmọ rẹ̀ ni Ṣemu, Hamu ati Jafẹti. Lẹ́yìn ìkún omi, àwọn mẹtẹẹta bí ọmọ tiwọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 10

Wo Jẹnẹsisi 10:1 ni o tọ