Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun pàṣẹ pé kí awọsanma wà láàrin omi, kí ó pín omi sí ọ̀nà meji, kí ó sì jẹ́ ààlà láàrin omi tí ó wà lókè awọsanma náà ati èyí tí ó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:6 ni o tọ