Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun pàṣẹ pé kí ilẹ̀ mú oríṣìíríṣìí ẹ̀dá alààyè jáde: oríṣìíríṣìí ẹran ọ̀sìn, oríṣìíríṣìí ohun tí ń fàyà fà lórí ilẹ̀ ati oríṣìíríṣìí ẹranko ìgbẹ́, ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:24 ni o tọ