Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 9:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọgbọ́n ti kọ́lé,ó ti gbé àwọn òpó rẹ̀ mejeeje nàró.

2. Ó ti pa ẹran rẹ̀,ó ti pọn ọtí waini rẹ̀,ó sì ti tẹ́ tabili rẹ̀ kalẹ̀.

3. Ó ti rán àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀kí wọn lọ máa kígbe lórí àwọn òkè láàrin ìlú pé:

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 9