Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 30:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọ̀rọ̀ Aguri, ọmọ Jake ará Masa nìyí:Ọkunrin yìí sọ fún Itieli ati Ukali pé,

2. “Nítòótọ́ mo jẹ́ aláìmọ̀kan jùlọ ninu gbogbo eniyan,n kò ní òye tí ó yẹ kí eniyan ní.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 30