Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 3:33-35 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Ègún OLUWA wà lórí ìdílé ẹni ibi,ṣugbọn a máa bukun ibùgbé àwọn olódodo.

34. A máa fi àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn ṣe ẹlẹ́yà, ṣugbọn a máa fi ojurere wo àwọn onírẹ̀lẹ̀.

35. Ọlọ́gbọ́n yóo jogún iyì,ṣugbọn ojú yóo ti òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 3