Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 29:26-27 BIBELI MIMỌ (BM)

26. Ọ̀pọ̀ ń wá ojurere olórí,ṣugbọn OLUWA níí dáni ní ẹjọ́ òdodo.

27. Olódodo a máa kórìíra alaiṣootọ,eniyan burúkú a sì kórìíra eniyan rere.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 29