Nígbà tí olódodo bá di eniyan pataki,àwọn eniyan a máa yọ̀,ṣugbọn nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè,àwọn eniyan a máa kérora.