Ó lè gbìyànjú láti fi ẹ̀tàn pa àrankàn rẹ̀ mọ́,ṣugbọn ìwà burúkú rẹ̀ yóo hàn ní àwùjọ gbogbo eniyan.