Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 25:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Olódodo tí ó fi ààyè sílẹ̀ fún eniyan burúkúdàbí odò tí omi rẹ̀ dàrútabi kànga tí a da ìdọ̀tí sí.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 25

Wo Ìwé Òwe 25:26 ni o tọ