Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 25:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn òwe mìíràn tí Solomoni pa,tí àwọn òṣìṣẹ́ Hesekaya ọba Juda kọ sílẹ̀ nìwọ̀nyí.

2. Ògo ni ó jẹ́ fún Ọlọrun láti fi nǹkan pamọ́,ṣugbọn ògo ló sá tún jẹ́ fún ọbaláti wádìí nǹkan ní àwárí.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 25