Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 23:32-34 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Nígbà tí ó bá yá, á máa buni ṣán bí ejò,oró rẹ̀ á sì dàbí ti ejò paramọ́lẹ̀.

33. Ojú rẹ yóo rí nǹkan àjèjì,ọkàn rẹ á máa ro èròkerò.

34. O óo dàbí ẹni tí ó dùbúlẹ̀ lórí agbami òkun,bí ẹni tí ó sùn lórí òpó ọkọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 23