Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 23:11-14 BIBELI MIMỌ (BM)

11. nítorí pé Olùràpadà wọn lágbára,yóo gba ìjà wọn jà.

12. Fi ọkàn rẹ sí ẹ̀kọ́, kí o sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ìmọ̀.

13. Bá ọmọde wí;bí o bá fi pàṣán nà án, kò ní kú.

14. Bí o bá fi pàṣán nà án,o óo gba ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́ ikú.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 23