Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 2:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Nítorí àwọn tí wọ́n dúró ṣinṣin ni wọn yóo máa gbé ilẹ̀ náà,àwọn olóòótọ́ inú ni yóo máa wà níbẹ̀,

22. ṣugbọn a óo pa ẹni ibi run lórí ilẹ̀ náà,a óo sì fa alárèékérekè tu kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 2