Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 2:20-22 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Nítorí náà, máa rìn ní ọ̀nà àwọn eniyan rere,sì máa bá àwọn olódodo rìn.

21. Nítorí àwọn tí wọ́n dúró ṣinṣin ni wọn yóo máa gbé ilẹ̀ náà,àwọn olóòótọ́ inú ni yóo máa wà níbẹ̀,

22. ṣugbọn a óo pa ẹni ibi run lórí ilẹ̀ náà,a óo sì fa alárèékérekè tu kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 2