Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 19:27-29 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Ọmọ mi, bí o bá kọ etí dídi sí ẹ̀kọ́,o óo ṣìnà kúrò ninu ìmọ̀.

28. Ẹlẹ́rìí èké a máa kẹ́gàn ìdájọ́ òtítọ́,eniyan burúkú a máa jẹ ẹ̀ṣẹ̀ bí ẹni jẹun.

29. Ìjìyà ti wà nílẹ̀ fún ẹlẹ́yà,a sì ti tọ́jú pàṣán sílẹ̀ fún ẹ̀yìn òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 19