Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 17:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Kí á fi alaafia jẹun, láìsí ọbẹ̀,ó sàn ju kí á máa fi ẹran jẹun pẹlu ìyọnu lọ.

2. Ẹrú tí ó bá mọ ìwà hù, yóo di ọ̀gá lórí ọmọ tí ń hùwà ìbàjẹ́,yóo sì jókòó pín ninu ogún bí ẹni pé ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ni.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 17