Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 11:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Èso olódodo ni igi ìyè,ṣugbọn ìwà aibikita fún òfin a máa paniyan.

31. Bí a óo bá san ẹ̀san fún olódodo láyé,mélòó-mélòó ni ti eniyan burúkú ati ẹlẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 11