Àwọn òwe Solomoni nìwọ̀nyí:Ọlọ́gbọ́n ọmọ á máa mú kí inú baba rẹ̀ dùn,ṣugbọn òmùgọ̀ ọmọ a máa kó ìbànújẹ́ bá ìyá rẹ̀.