Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀,ṣugbọn àwọn òmùgọ̀ a máa pẹ̀gàn ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 1

Wo Ìwé Òwe 1:7 ni o tọ