Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 1:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn òwe tí Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli pa,

2. kí àwọn eniyan lè ní ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́,kí òye ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lè yé wọn,

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 1