Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó mọ àkókò tirẹ̀. Bíi kí ẹja kó sinu àwọ̀n burúkú, tabi kí ẹyẹ kó sinu pańpẹ́, ni tàkúté ibi ṣe máa ń mú eniyan, nígbà tí àkókò ibi bá dé bá wọn.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 9

Wo Ìwé Oníwàásù 9:12 ni o tọ