Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ, sùúrù sì dára ju ìwà ìgbéraga lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7

Wo Ìwé Oníwàásù 7:8 ni o tọ