Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan burúkú gan-an ni èyí pàápàá jẹ́; pé bí a ṣe wá bẹ́ẹ̀ ni a óo ṣe lọ. Tabi èrè wo ni ó wà ninu pé asán ati ìmúlẹ̀mófo ni gbogbo làálàá wa láyé.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 5

Wo Ìwé Oníwàásù 5:16 ni o tọ